Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence)
Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun onibo/olo po oro-ise Gbolohun Abode/Ele yo oro-ise Gbolohun Abode je gbolohun ti kii gun Gbolohun Abode kii ni ju oro-ise eyokan lo. Apeere, Bata re […]
Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence) Read More »