ETO ISELU ODE-ONI
Ni aye ode-oni eto iselu ti yato patapata is ti aye atijo. Ni aye ode-oni, eto iselu ti aye ode-oni ni a n lo gomina ni Olori ati alase ni ilu kookan ti o si ni awon komisanna ti won jo n tuko eto ilu. Loooto ni awon oba si wa sugbon won ko ni […]